You are on page 1of 1

1-Ògún àjò e mònrìwó, aláàkòró àjò e mònrìwó. Ògún pa lè pa lóònòn.

Elé ki fí èjè wè
1- Àwa nsiré Ògún ó, èrù jojo. Áwa nsiré Ògún ó, èrù jojo. Èrùnjéjé
2- Ògún nítà ewé rè. Bá Òsóòsì l'oko rí náà lóòde
3- Aláàkòró elénun aláàkòró elénun ó. Ae ae ae aláàkòró elénun ó
4- A l'Ògún méje Ìré, aláàda méji, méji
5- Ìjà pè lé ìjà pè lé ìjà. Aláàkòró Oníré
6- E mònrìwò l'aso e mònrìwò
7- Àkòró gbà àgádá. Ògún gbà àgádá é
8- Ògún a kò fíríì. bis A pàdé l'ònòn kí a wò
10- Oní kòtò n'ilé Ògún. Ó ni àwa apàjà, oní kòtò ó pa òbe
11- Ògún ní kòtò gbálé mònrìwò àwúre
12- Oní kòtò n'ilé Ògún. Àwúre dúró do onìjà. E Àwúre dúró do onìjà
13- A imòn nilé a imòn e dàgòlóònòn kó yá
14- Mòn gbé Ògún aráayé, àigbè Ògún sòro. Mòn gbé, mòn gbè Ògún sòro
15- Dé àwa dé lóòde kòrò ngbè lé. Lákòró Ògún jà àkòró ngbè lé ó
16- Apàjà l'ònòn Ògún máa sá akìí bèrù já. Apàjà Ògún máa sá akìí bèrù já
17- Ké kìkì alákòró ké kìkì alàkòró Olúàiyé Kí fé Ògún àkòró OnÍré, Oluàiyé ìtònnón. Lákòró
OnÍré
18- Ògún Oníré ó àkòró onÍré oòré gèè dé. Aare (chalare)Ògún OnÍré oòrè gèè dé
19- Ògún sékórè ndé, ó sékórè
20- E ònòn kóró nsiré idà, e ònòn kóró nsiré idà
21- Ògún pa ó lépa, akòró pa ó jà're
22- Kàtà-kàtà ó gbìn méje. Ó gbìn méje ònòn gbogbo
23- Ògún sékórè kà ni isu ki ó dé. Ògún sékórè kà ni isu l'ònòn
24- E pa ní Ògún ki má ra àwa, e pa ní Ògún ki àwa awo. Ògún OnÍré e pa ní Ògún ki àwa awo
25- Àwa dé èyin, aworò rí Ògún je ajá
26- Érù jà olóònòn dé, èrú jà olóònòn dé. Ògun àkòró ki ìjá èrù jà olóònòn dé
27- Pa nyin òbe Ògún pa nyin òbe
28- Epo ni obè, epo mu ó, epo ni obè, epo mu ó
29- Aláadà méjì ó sìn imonlè, fí èjè wè aláàkòró. A pàdé ó níbí ìjà, OnÍré Ògún dé jà o. Rere ire
Íré, Ògún jà, àwa pé e àgò l'ònón. Kò mo nrí ìjà rè ó
30- E omo àwa omodé e ngbèlé ki a awo. E àwa fún àgò l'ònòn Oníré Ògún jà ó. Ògún dé a
rere ire Íré Ògúnjà, àkòro wa dé a rere ire ilé Ògúnjà ó
31- Ògún OnÍré, onÍré Ògún, aláàkòró onÍré. Oba dé òrun
32- Ògún ní aláàgbède, mònrìwò ode, ode mònrìwò
33- E onibodè òrun ò e oníbodè òrun ó. Ni ònòn lá ni ònòn là e mònrìwò
34- Ògún kò l'aso, e mònrìwò ònòn. E Ògún kò l'aso, e mònrìwò ònòn